Thursday, 29 September 2016

AWON ERANKO ILE YORUBA



ANIMALS- AWON ERANKO

1. lion - kìnìùn
2. lizard - alàngbá
3. camel - ràkúnmí
4. donkey - kẹtẹkẹtẹ
5. elephant - erin
6. wolf - ìkòokò
7. hedgehog – túrùkú
8. snake- ejò
9. cat - olóngbo
10. horse - ẹşin
11. goat - ewurẹ
12. sheep – àgùtàn;  ewe – àgùtàn; ram - àgbò
13. deer - èsúró
14. monkey - ọbọ
15. leopard - amọtẹkun
16. tiger - ẹkun
17. guinea pig - ẹmö      
18. hamster - aşin
19. dog - ajá
20. rabbit - ehoro
21. hare – ehoro igbo
22. tortoise – ìjàpá; ahun
23. fox - kõlõkõlõ
24. grasscutter - õ
25. buffalo - ẹfọn
26. squirrel - ọkẹrẹ
27. snail - ìgbìn
28. fish - ẹja
29. wall gecko - ọmọọle
30. turtle – ahun odò
31. lobster/prawn/crayfish - edè
32. chameleon - ọgà
33. squirrel - ọkẹrẹ
34. Iguana – à-n-tà
35. hippopotamus – erinmilokun; erin-odó
36. crocodile - õni
37. alligator - ẹlëgungun

AWON EYE ATI OHUN ABIYE YORUBA

          
BIRDS-AWON EYE

  1. owl -òwìwí
  2. bat - àdán
  3. bush fowl - àparò
  4. sparrow - ẹgà                        
  5. kite - àşá
  6. hawk - àşádì
  7. eagle – àwòdì
  8. vulture - igún
  9. kiwi - adiẹ-odò
  10. duck - pẹpẹyẹ
  11. guinea fowl - ẹtù; awó
  12. fowl - adiẹ; cock -akukọ; hen - obídiẹ; chick - òròmọdìẹ
  13. parrot - ayékòót
  14. wood pecker – ẹyẹ àkókó
  15. ostrich – ògòngò
  16. peacock – ọkín
  17. turkey – tòlótòló
  18. dove – àdàbà
cuckoo – òdèrè

Tuesday, 27 September 2016

ASA ISOMOLORUKO NI ILE YORUBA



ASA ISOMOLORUKO NI ILE YORUBA
Yoruba bo won ni ile laawo ka too so omo loruko. Isele to ba n sele lagbo ile ti a ti bimo tabi ona ti omo ba gba waye maa n se atokun oruko ti a o soo. Bakan naa ni ibi ti a bi omo si ati asiko , ojo, esin abbl., lo maa n niise pelu oruko ti a o so omo ni ile Yoruba.
ALAYE NIPA IRU AWON OMO WONYII
1.         Omo ti o mu ese waye ni ____(ige)
2.         Omo tio ni ika mefa ni ­­______(olugbodi)
3.         Omo ti a bi si oju ona ni _____(abiona)
4.         Omo ti a bi nigba ti baba re ko si nile ni ____(bidemi)
5.         Omo ti irun ori re ta koko ni _____(dada)
6.         Omo ti o wa ninu apo nigba ti a bii ni _____(oke)
7.         Omo ti o gbe ibi ko orun waye ni _____(ojo/aina)
8.         Omo meji ti a bi leeka naa ni ____(taye ati kehinde)
10.      Ta ni alaba? (Omo ti a bi le idowu)
11.      Omo ti baba re kun i kete ti a bii tan ni ____(babarimisa)
12.      Omo ti o kere pupo nigba ti a bii ni _____(kiyeseni)
13.      Iru omo wo ni a n pe ni kasimaawoo?
14.      Iru omo won  a n pen i aja? Abiku omo.
Bawo ni a se n fi awon nnkan wonyii se adura nibi isomoloruko?
11.   Aadun- ki aye omo naa ladun
22.    Oyin- ki aye omo naa loyin
33.    Ataare-ki aye maa soro re nire, ko sin i omo pupo bii ataare
44.    Orogbo- ko dagba, ko dogbo
55.    Obi- ki obi bi iku ati arun danu
66.    Eja gbigbe- otutu kii meja lale odo, aye ko nii gbona moo
77.    Eku gbigbe- ki eku maa ke bii eku, ki eye maa ke bii eye, ki aye re maa lo daadaa
88.    Ireke- adun nit i ireke ki aye re ladun
  9.Omi-ki aye mase ba omo tuntun naa se ota,nitori pe a kii ba omi sota.
110.Oti- aye omo tuntun naa ko gbodo ti