Tuesday 27 September 2016

ASA ISOMOLORUKO NI ILE YORUBA



ASA ISOMOLORUKO NI ILE YORUBA
Yoruba bo won ni ile laawo ka too so omo loruko. Isele to ba n sele lagbo ile ti a ti bimo tabi ona ti omo ba gba waye maa n se atokun oruko ti a o soo. Bakan naa ni ibi ti a bi omo si ati asiko , ojo, esin abbl., lo maa n niise pelu oruko ti a o so omo ni ile Yoruba.
ALAYE NIPA IRU AWON OMO WONYII
1.         Omo ti o mu ese waye ni ____(ige)
2.         Omo tio ni ika mefa ni ­­______(olugbodi)
3.         Omo ti a bi si oju ona ni _____(abiona)
4.         Omo ti a bi nigba ti baba re ko si nile ni ____(bidemi)
5.         Omo ti irun ori re ta koko ni _____(dada)
6.         Omo ti o wa ninu apo nigba ti a bii ni _____(oke)
7.         Omo ti o gbe ibi ko orun waye ni _____(ojo/aina)
8.         Omo meji ti a bi leeka naa ni ____(taye ati kehinde)
10.      Ta ni alaba? (Omo ti a bi le idowu)
11.      Omo ti baba re kun i kete ti a bii tan ni ____(babarimisa)
12.      Omo ti o kere pupo nigba ti a bii ni _____(kiyeseni)
13.      Iru omo wo ni a n pe ni kasimaawoo?
14.      Iru omo won  a n pen i aja? Abiku omo.
Bawo ni a se n fi awon nnkan wonyii se adura nibi isomoloruko?
11.   Aadun- ki aye omo naa ladun
22.    Oyin- ki aye omo naa loyin
33.    Ataare-ki aye maa soro re nire, ko sin i omo pupo bii ataare
44.    Orogbo- ko dagba, ko dogbo
55.    Obi- ki obi bi iku ati arun danu
66.    Eja gbigbe- otutu kii meja lale odo, aye ko nii gbona moo
77.    Eku gbigbe- ki eku maa ke bii eku, ki eye maa ke bii eye, ki aye re maa lo daadaa
88.    Ireke- adun nit i ireke ki aye re ladun
  9.Omi-ki aye mase ba omo tuntun naa se ota,nitori pe a kii ba omi sota.
110.Oti- aye omo tuntun naa ko gbodo ti

38 comments:

  1. It's very useful and helpful.
    Thanks

    ReplyDelete
  2. It's very useful and helpful
    God will bless you
    Thanks.

    ReplyDelete
  3. It's OK and helpful. I hope to see more of this .Thanks.

    ReplyDelete
  4. oruko wo ni an oe awon omo ti agbegilere ba bi

    ReplyDelete
  5. E seun, ajinde ara yoo maa je o

    ReplyDelete
  6. Kini a n pe omo to o fi idiJ wa lati inu iya? re

    ReplyDelete
  7. Kini a n pe omo ti o fi idi Jade wa lati inu iya re

    ReplyDelete
  8. Mi o Mo Awon kan ninu
    e o
    ESE gan ni o

    ReplyDelete
  9. please can you give more detail.
    Thanks.

    ReplyDelete
  10. If not for you I can not do my homework

    ReplyDelete
    Replies
    1. Seriously I also needed this for my homework and I am very grateful😊😊😊😊

      Delete
  11. Thanks😉😉😉

    ReplyDelete
  12. Thanks so much it really helped in explaining this topic to my students

    ReplyDelete
  13. Muse and inspiration to my research work

    ReplyDelete
  14. Muse and inspiration to my research work

    ReplyDelete